Àǹfààní láti kọ́wèé lọ́fẹ̀ẹ́: Àwọn ènìyàn méjìlé-láàdọ́rin ṣetán láti gbéra ní…
Àwọn ọmọ Nàìjíríà méjìlé-láàdọ́rin ti wọn fun ni Àǹfààní láti kọ́wèé lọ́fẹ̀ẹ́ ni orilẹ-ede Hungary lo ti ṣetán láti gbéra ní Nàìjíríà ni ọjọ kejile-logun, oṣu kẹsan an 2023.
Minisita ipinlẹ fun eto ẹkọ ni…