APC Anambra Ṣe Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Ìforúkọsílẹ̀ Pẹ̀lú Ìmọ-Ẹ̀rọ Ní Gbogbo Ìpínlẹ̀ Náà
Ẹgbẹ́ òṣèlú 'All Progressives Congress APC' ní Ìpínlẹ̀ Anambra tí ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìforúkọsílẹ̀ pẹ̀lú imọ-ẹ̀rọ ní gbogbo ìpínlẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó wà tẹ́lẹ̀ àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tuntun, gẹ́gẹ́ bí apá kan lára àwọn ìsapá wọn láti gbá…