Mínísítà Ìdárayá Kí Ààrẹ Túntún Tí Á Fibò Yàn Kú Oríìré
Mínísítà fún ìdàgbàsókè àwọn ọdọ àtí èrè ìdárayá, Sunday Dare tí kì Olúbóri nínú Ìdìbò Ààrẹ tí ọdún yìí, olùdíje fún ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC, Asiwaju Bola Ahmed Tinubu.
Ìkíni rẹ̀ tó wà nínú Gbólóhùn tí a samisi pé…