Gómìnà Mákindé fi ìdí ikú gómìnà nígbà kan rí, Akálà múlẹ̀
Gómìnà Ṣèyí Mákindé ti Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fi ìdí ikú gómìnà tẹ́lẹ̀ nígbà kan rí, Adébáyò Àlàó-Akálà múlẹ̀.
Makinde jabọ ọrọ iku naa nigba ti wọn pe e lati sọrọ inu rere nibi adura ijọsin ti n lọ lọwọ fun awọn…