Àgùnbánirọ̀ ṣe ayẹyẹ ọdún méjìdín-láàdọ́ta
Àwọn àgùnbánirọ̀ láti ibùdó mẹ́tàdín-lógójì jákèjádò orílẹ̀-èdè ti fakọyọ nípa ìfìfẹ́ hàn sí orílẹ̀-èdè, ní èyítí ó jẹ́ ìfilọ́lẹ̀ ètò ọ̀hún láti ọdún méjìdín-lógójì sẹ́yìn, nípa yíyan bí…