Àdínkù owó epo ilẹ̀: Ìjọba Nàìjíríà ṣèpàdé pẹ̀lú ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ kátàkár̀a
Ìjọba Nàìjíríà n ṣepade pẹ̀lú àwọn aṣojú ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ kátàkár̀a (TUC), lọ́wọ́ báyìí, ní gbọ̀ngàn ààrẹ, ní Villa, Abuja.
Ìpàdé tó bẹ̀rẹ̀ ní dédé agogo mẹ́rin ìrọ̀lẹ́, yóò dá lórí ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀…