Adarí ológun rọ àwọn ọmọ ogun láti ní ìgboyà àti ìfọkànsìn
Wọ́n ti rọ àwọn ọmọ ogun láti ní ìgboyà, ìfọkànsìn, ìfaragba lẹ́nu iṣẹ́ wọn.
Adari ọmọ ologun 4 Special Forces, Ajagun Hillary Nzan gba imọran yii nigba ti o n ba awọn ikọ pataki 167 Special Forces Battalion, sọrọ ni ibugbe awọn…