Adarí ológun gbóríyìn fún àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà
Asojú Adarí Ìgbìmọ̀ àti Adarí ológun (Ag HoM/FC) ti Ọmọ ogun ààbò Abyei fìdíhẹẹ́ fún Àjọ ìṣọ̀kan (UNISFA), Ajagun Benjamin Sawyer gbóríyìnti fún ìmọṣẹ́, ìfarasisẹ́, àti ìsiṣẹ́ lọ́nà tó tọ́ àwọn ọmọ ogun…