Adarí Nàìjíríà yóò dúró ọ̀ṣẹ̀ kan si ní London
Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò dúró ọ̀sẹ̀ kan síi ní London, United Kingdom,bí Dókítà eyín rẹ̀ ṣe sọ,tí ó sì ti ń ṣètọ́jú rẹ̀.
Dókítà ní láti ṣètọ́jú ààrẹ fún ọjọ́ márùn ún mìíràn tí ó sì ti bẹ̀rẹ̀…