Adarí àgbà fún àwọn ọmọ ogun ojú omi fara gbọgbẹ́ ní Ukraine
Olùdarí àgbà fún àwọn ọmọ ogun ojú omi Òkun Dúdú ní Rọ́síà ti fara gbọgbẹ́ ní orílẹ̀-èdè Ukraine, gómìnà Sevastopol ló kéde rẹ̀ ní ọjọ́ àìkú.
Post-Captain Andrei Paliy, igbakeji alakoso ọkọ oju-omi, padanu ẹmi…