Adarí, Igbákejì, bẹnu àtẹ́ lu ìpànìyàn ìpínlẹ̀ Plateau
Adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú, Ọ̀gbẹ́ni Abbas Tajudeen àti Igbákejì Adarí, Ọ̀gbẹ́ni Benjamin Kalu, ti bẹnuàtẹ́ lu ìkọlù tó ṣẹlẹ̀ láìpẹ̀ yìí ní agbègbè Ruwi, Manguna, Daffo, Josho àti Hurti ní ìjọba ìbílẹ́ Bokkos ti…