Abúgbàmù Kankan kò wáyé ní ilé ìfọpo Warri – NNPCL
Ilé iṣẹ́ tí ń rísí ọ̀rọ̀ epo ilẹ̀ lórílẹ̀-èdè (NNPC), ti tako ìròyìn abúgbàmù ní ilé iṣé ìfọpo Warri (WRPC), tí wọ́n sí ṣàlàyé pé àwọn àtúnṣe ètò tó máa ń wáyé lóórè kóòrè nílé iṣẹ́ náà ló ń lọ…