Ààrẹ Tinubu gbàlejò Super Eagles
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ́lù Super Eagles ti bá Ààrẹ Bọla Tinubu lálejò ní ilé ìgbìmọ̀, ní ilé orílẹ̀-èdè, ní Abuja.
O n gbalejo wọn lẹyin ikopa wọn ninu ipele ikẹyin ninu idije ife awọn orilẹ ede Adulawọ (AFCON) 2024,…