Ààrẹ Tinubu gba gómìnà ìpínlẹ̀ Enugu lálejò
Ààrẹ Bọla Tinubu ṣèpàdé pẹ̀lú gómìnà Peter Mbah ti ìpínlẹ̀ Enugu, ní ilé iṣẹ́ ààrẹ Villa, Abuja.
Lẹyin ipade naa ti awọn oniroyin fẹ baa sọrọ, ko fesi kankan.
Ṣugbọn ifọrọjomitoro ọrọ oun ati aarẹ ko le ja lori…