Ààrẹ Tinubu fi Keyamo rọ́pò Mínísítà Kano tí wọ́n yàn
Ààrẹ Bọla Tinubu ti yọ Mínísítà Kano tí wọ́n yàn, Dokita Maryam Shettima, tí ó sì fi Dokita Mariya Mahmoud tó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ kannáà rọ́pò.
Ààrẹ tun yan minisita fun iṣẹ ati igbanisiṣẹ nigba kan ri, Festus Keyamo,…