Ààrẹ Tinubu, àwọn adarí àgbáyé kópa nínú ìgorí ìtẹ́ Pope Leo kẹrìnlá
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti darapọ̀ mọ́ àwọn adarí lágbàáyé ni St Peter’s Basilica fún ìgorí ìtẹ́ Pope Leo kẹrìnlá, tí ó fi ìgbà kan jẹ́ àdarí Kadinali Robert Francis Prevost, ó jẹ́ ọmọ bíbí inú Chicago, tí ó sì…