Ààrẹ Guinea Bissau di alágaa àjọ ọrọ̀-ajé àwùjọ adúláwọ̀
Wọ́n ti yan Ààrẹ Umaro Sissoco Mbalo orílè-èdè Guinea ní ọjọ́ Àìkú gẹ́gẹ́ bí Alágaa tuntun àwọn ààrẹ orílè-èdè ti Àjọ ọrọ̀-ajé àwùjọ iwọ̀-oòrùn Adúláwọ̀,ECOWAS.
Alaga Ajọ ti n lọ, Aarẹ Nana Akufo-Addo…