Ààrẹ Bùhárí búra fún àwọn akọ̀wé aláṣẹ mẹ́ta
Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti búra fún àwọn akọ̀wé aláṣẹ mẹ́ta kan.
Iṣẹlẹ naa waye ni Ọjọru, ni gbangan Igbimọ ni Villa,ibudo aarẹ,ni ilu Abuja.
Awọn Akọwe Alaṣẹ Tuntun naa n: Lydia Jafiya lati Ipinlẹ Adamawa; Udom Ekenam lati…