A yóò ṣa gbogbo ipá wa láti ran Sẹ́nétọ̀ tó wà nínú làásìgbò lọ́wọ́
Olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-ṣòfin Nàìjíríà, Aṣojú Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà sọ pé òun ti pá láṣẹ fún Ìgbìmọ̀ aṣojú Nàìjíríà ní UK, láti fún Sẹ́nétọ̀ Ike Ekweremadu, ní gbogbo ìrànlọ́wọ́ tí ó nílò lórí…