A kò kóóríra ẹ̀sìn kankan o
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé àwọn òfin àti ìlànà orílẹ̀-èdè kò fàyègba èyíkéyìí irú òfin ẹ̀sìn tàbí inúnibíni ẹ̀sìn.
Minisita fun eto ibaraẹnisọrọ ati Aṣa,Lai Muhammad sọ eyi nibi ifọrọwanilẹnuwo pẹlu Voice of…