Ọjọ́ Ìrántí Àwọn Ọmọ-ogun Ọdún 2026 Bẹ̀rẹ̀
Àyajọ́ ayẹyẹ ìrántí àwọn ọmọ-ogun Ọdún 2026 ti bẹ̀rẹ̀ ní gbogbo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, O bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn àdúrà pàtàkì ní Mọ́sálásí Orílẹ̀-èdè ní Abuja, àwọn mọ́sálásí àárín gbùngbùn ní àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì, àti tí àwọn ẹgbẹ́ ológun…