Ààrẹ Tinubu Wá Ojútùú Sí Wàhálà Àti Ìpànìyàn Tí Ó Ń Wáyé Ní Ìpínlẹ̀ Plateau
Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti pè fún fífi òpin sí wàhálà àti rúkè-rúdò tí ó ń sẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Plateau, ó ké sí àwọn Ọba Alaye, olórí Ẹ̀sìn, Olósèlú jákè-jádò Ìpínlẹ̀ náà láti fọwọ́sowọ́pọ̀ lójúnà àti…