Take a fresh look at your lifestyle.

Kòsí Ìgbàláyè Fún Ọkọ̀ Akérò Pẹ̀lú Ọ̀dà Ayédèrú Láti Sisẹ́ Ní Abuja- Nyesom Wike

Mínísítà Ìlú Abuja, Ọ̀gbẹ́ni Nyesom Wike sọ pé ìjọba yóò fi òfin de àwọn ọkọ̀ akérò tí kò ní ọ̀dà tí ìjọba fi ọwọ́ fí láti siṣẹ́ ní òpópónà gbogbo ní ìlú Abuja Wike síṣọ lójú ọ̀rọ̀ náà nígbà…

Ààrẹ Tinubu Fi Àrídájú Hàn Láti Gbógunti Ìwà Àjẹbánu Nígbà Tí Ó Gbàlejò Adarí…

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti sàfihàn ìgbáradì ìsèjọba rẹ̀ láti gbógunti ìwa àjẹbánu àti àwọn ìwà burúkú míràn láwùjọ   Ó sàlàyé gẹ́gẹ́ bí ó se ṣe pàtàkì nínú ojúse ìjọba…

Mímú Ìdàgbàsókè Bá Ètò Ọ̀gbìn Se Pàtàkì Fún Àwọn Orílẹ̀-èdè Adúláwọ̀ láti Tán…

Lójúnà àti tán ìsòro ebi, kí oúnjẹ sì pọ̀ yanturu, àjọ tí ó wà fún mímú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn ti pàrọwà sí àwọn Orílẹ̀-èdè adúláwọ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọ̀gbìn   Àwọn àjọ tí ọ̀rọ̀…

Wọ́n Ti Fi Ẹ̀sùn Ìpànìyàn Kan Olórí Ẹgbẹ́ Òkùnkùn Ní Orílẹ̀-èdè Kenya Látàrí…

Adájọ́ ti pàṣẹ kí olórí ẹgbẹ́ òkùnkùn ní Orílẹ̀-èdè Kenya, Paul Mackenzie àti àwọn ọgbọ̀n míràn lọ se àyẹ̀wò ọpọlọ  síwájú kí wọ́n tó kojú ẹ̀sùn ìpànìyàn  níbi tí wọ́n ti sekúpa àwọn ọmọdé tí ó dín díẹ̀…

Àjọ INEC Ìpínlẹ̀ Gombe Kéde Ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n Osù Kẹrin Fún Ìdìbò Ìjọba Ìbílẹ̀

Àjọ Elétò Ìdìbò ti kéde ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù kẹrin ọdún 2024 gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe, Muhammadu Inuwa Yahaya fi ọwọ́ sí, fún síse ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ náà   Nígbà tí…

Gbajú-gbajà Oníròyìn Ayọbolu Di Ẹni Ọgọ́ta Ọdún, Ààrẹ Tinubu Dáwọ̀ọ́ Ìdùnnú Pẹ̀lú Rẹ̀

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti  dáwọ̀ọ́ ìdùnnú pẹ̀lú olùfọ̀rọ̀léde rẹ̀ tẹ́lẹ̀rí, ọ̀gbẹ́ni Sẹgun Ayọbolu níbi ayẹyẹ ọgọ́ta ọdún tí ó ṣe                              Agbẹnusọ ààrẹ, Ajuri Ngalale ni ó sọ ọ̀rọ̀ náà nínú…
button