Ọmọ Ogun Iran Ran Russia Lọ́wọ́ Láti Ṣe Àkọlù Sí Ukraine – America Fi Ẹ̀sùn Kàn
Ilẹ̀ America ti fi ẹ̀sùn kàn pé àwọn ọmọ ogun orílẹ̀ èdè Iran wà ní àgbègbè afárá Crimea níbi tí wọ́n ti ń ran orílẹ̀ èdè Russia lọ́wọ́ láti ṣe àkọlù sí orílẹ̀ èdè Ukraine.
Agbenusọ orílẹ̀ èdè…