Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Gómìnà Jẹ́jẹ̀ẹ́ Àtìlẹyìn Fún Ilé Iṣẹ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn

Àjọ àpérò àwọn gómìnà ti jẹ́jẹ̀ẹ́ àtìlẹyìn àti ìpinnu wọn láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ilé iṣẹ́ tí ó ń mójú tó gbígba ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn láàyè. Adelé alága àjọ náà, gómìnà ìpínlẹ̀ Sokoto ní…

Ọ̀gá Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Kwara Gbé Òsùbà Fún Àjọ Tí Ó Ń Gbógun Ti Ìwà Àjẹbánu

Ọ̀gá Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Kwara, Odama Paul ti gbé oríyìn fún àjọ tí ó ń gbógun ti ìwà ìbàjẹ́ àti àjẹbánu ní ìpínlẹ̀ náà. Ó ju ọwọ́ káre sí àjọ náà nígbà tí ó se àbèwò ẹ pẹ̀lẹ́ ní ibẹ̀yan sí…

Ẹgbẹ́ Àwọn Ìyàwó ọlọ́pàá Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Tí Ó Lùgbàdì Omíyalé Ní Ìpínlẹ̀…

Ẹgbẹ́ àwọn ìyàwo ọlọ́pàá ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí se ìrànlọ́wọ́ ohun ìrẹnilẹ́kún tí ó tó mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n náírà fún àwọn tí ó lùgbàdì omíyalé ní ìpínlẹ̀ Kogi Ààrẹ ẹgbẹ́ náà tí…

Àwọn Ọba Alayé Kéde Àtìlẹyìn Fún Sá à Elẹ́ẹ̀kejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara

Àgbájọpọ̀ àwọn ọba alayé, olórí lájọ-lájọ àti àwọn sàràkí ènìyàn ní ìpínlẹ̀ Kwara ti kéde àtìlẹyìn wọn fún sá à ẹlẹ́ẹ̀kekì gómìnà AbdulRahaman Abdulrasaq látàrí àseyọrí rẹ̀. Ìfiléde ọ̀rọ̀…
button