Ilé Aṣòfin Èkó tẹnu mọ́ pàtàkì ṣíṣe ìdásílẹ̀ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀
Ile Igbimọ Aṣofin Ipinlẹ Eko ti tẹnu mọ pataki ṣiṣe idasilẹ ọlọpaa Ipinlẹ lati le gegi dina bi wọn ṣe n pa awọn eniyan nipakupa ati awọn ipenija aabo lawujọ paapaa Ipinlẹ Eko.
Oludari Ile Igbimọ Aṣofin Ipinlẹ Eko,…