Nàìjíríà Tí Bẹ̀rẹ̀ Ìsinmi Ìbímọ Fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba Ọkùnrin
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí bẹ̀rẹ ìsinmi lẹnu iṣẹ́ ọlọjọ mẹrinla fún àwọn ọkùnrin òṣìṣẹ́ ìjọba tí ìyàwó wọn bímọ.
Èyí ní yóò bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́bí àkọlé ìwé àwọn òṣìṣẹ́ tí wọ́n pé àkọlé rẹ̀ ní "àkọsílẹ̀ ọjọ́ ìsinmi lẹ́nu ìṣẹ́ àwọn òṣìṣẹ́…