Ààrẹ Tẹlẹ Rí Orílẹ̀-èdè Comoros, Sambi Yóò Fí Ẹ̀wọn Gbéré Gbára
Ilé-ẹjọ́ kàn ní Comoros ní Ọjọ́ Àjé tí dá ẹ̀wọn gbéré fún Ààrẹ tẹlẹ rí Ahmed Abdullah Sambi fún iditẹ mọ ìlú.
Sambi ẹní ọdún mérinlélọgọ́ta (64) náà ní wọ́n dàjọ́ fún lórí títà ìwé irinna fún àwọn ènìyàn tí kò ní ìlú tó ngbé ní…