Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́ EU Kàn Kọ̀ Látí Ṣe Àdéhùn Lórí Ijẹniniya Tuntun Fún Orílẹ̀-èdè Russia

Àwọn orílẹ̀-èdè ọmọ ẹgbẹ́ European Union kùnà látí gbà àdéhùn lórí ìjìyà kẹsán fún orílẹ̀-èdè Russia ní ibí ijiroro wọ́n ní Ọjọ́rú, àwọn aṣojú ìjọba sọ bí àwọn Olùdarí EU ṣé ní àpéjọ ní Brussels ní Ọjọ́bọ̀ níbí ìpàdé ìkẹyìn wọ́n tí ọdún…

Uganda Fí Ẹsùn Kàn Tọkọtaya Ọmọ Amẹ́ríkà Kan Lórí Fífi Ìyà Jẹ̀ Ọmọdé

Àwọn Ọlọ́pàá Uganda sọ pé tọkọtaya ará Amẹ́ríkà kan tí wọ́n fí ẹ̀sùn kàn án ní Uganda pẹ̀lú “ìjìyà gbígbóná janjan” tí ọmọkùnrin ọmọ ọdún mẹ́wàá tí wọ́n ti gbà ṣọmọ. Àwọn ọmọ ọgbọ̀n ọdún lé méjì, ní wọ́n fí ẹ̀sùn kàn ní ọjọ́ Ẹtì tí…

Ìgbìmọ̀ Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Yìí Fọwọ́sí Iṣeduro Bílíọ̀nù Mẹ́sàn Lé Díẹ̀ Fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba

Ìgbìmọ̀ àwọn aláṣẹ tí Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìyè owó bílíọ̀nù Mẹ́sàn àtí díẹ̀ (N9.24b) fún iṣeduro fún àwọn òṣìṣẹ́ ní gbogbo àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba. Mínísítà fún ètò Ìṣúná, ati Ètò Orílẹ-èdè, Iyaafin Zainab Ahmed sọ èyí lẹyìn ìpàdé Ọjọ́rú tí…
button