Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbáṣepọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Orílè-èdè China Lórí Ètò Ọjà Àtí Ọ̀rọ̀ Àjé Yóò Tú Bọ́ Gòkè Sí

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣètò láti mú kí ìbáṣepọ̀ lórí ìṣòwò àti àwọn ìbátan ọ̀rọ̀-àjé gbòòrò sí pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè China fún ànfààní àwọn orílẹ̀-èdè méjèèjì. Èyí ní èrò láti mú kí ìwọn ìṣòwò láàrín Nàìjíríà àti China kún sí, kúrò…

Ìyànṣẹ́lódi: Ìjọ̀ba Nàìjíríà Àtí Ẹgbẹ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Tí Wá Ojútùú Sí Áìgbọ́ra-ẹni-yé

Áìgbọ́ra-ẹni-yé láàrín ìjọ̀ba Nàìjíríà àti ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ (Nigeria Labour Congress NLC and Trade Union Congress TUC) lórí yíyọ owó ìrànwọ́ orí èpò bẹntiroolu tí ń dì òun ìgbàgbé díẹ̀díẹ̀ látàrí bí àjọ òṣìṣẹ́ ṣé kéde ìtẹ̀síwájú iṣẹ́ ní…

Ẹ Bọ̀wọ̀ Fún Ìlànà Àti Ìfẹ Orílẹ̀-èdè Yìí Tẹ́ Bá Dì Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin – Ahmed Lawan

Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ògbéni Ahmed Lawan, so pé ṣáájú kí wọ́n tó yán àwọn Olùdarí ile-igbimo Aṣòfin kẹwàá pé, kí wọ́n bọ̀wọ̀ fún ìgbéga orílẹ̀-èdè ẹ̀tọ́ ìlú. Ó fí kùn ùn pé ìlànà Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin ṣé kókó…
button