NPFL: Kano Pillars Gbà Àwọn Alákòóso Túntún
Ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù Kano Pillars tí Nigeria Professional Football League (NPFL) tí kéde àwọn àdele alákòóso túntún.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abba Kabir Yusuf ló ṣe ìpinnu náà gẹ́gẹ́ bí ará àkitiyan láti mú kí ẹgbẹ́ náà sọjí lẹ́yìn tí wọ́n ti…