Yíyọ Owó-Ìrànwọ́ Orí Èpò Kúrò: Ijọba Nàìjíríà Ṣé ìdánilójú Ètò Ìrọrùn
Alága, Àjọ ètò ìrọrùn lórí yíyọ ìrànwọ́ orí èpò kúrò "Palliative Committee on Subsidy Removal" àtí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi, Dókítà Nasir Idris, tí fí dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lójú pé àwọn tí bẹ̀rẹ̀ ìgbìyànjú lójúnà látí ṣé ìdẹ́kun lórí…