Àwọn Aláṣẹ Nàìjíríà Fọwọ́ Sí Ìdásílẹ̀ Owó Àtìlẹ́yìn Àwọn Òun Àmàyédẹ̀rún
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí fọwọ́sí ìdásílẹ̀ owó àtìlẹ́yìn fún àwọn òun àmàyédẹ̀rún ti 'Infrastructure Support Fund (ISF)' fún gbogbo Ìpínlẹ̀ mẹrindinlogoji tí Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí ìgbésẹ látí pèsè ìrọrùn fún àwọn aráàlú…