Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Anambra Gbá Gómìnà Níyànjú Látí Yàn Adájọ Àgbà Túntún

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Anambra tí kepè Gómìnà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Charles Soludo, látí yàrá pèsè gbogbo àwọn ìbéèrè tó nílò fún yíyan àwọn adájọ ilé-ẹjọ́ gíga mẹwàá tí àwọn ìgbìmọ̀ ìdájọ tí Orílẹ̀-èdè NJC yìí fọwọsi fún ìpínlẹ̀…

Ààrẹ Tinubu Bú Ìyìn Fún Awọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu, ṣé àpèjúwe Òṣìṣẹ́ ìjọba gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rọ́ ìṣètò àti ìmúṣẹ ṣé àwọn ìlànà àti ètò ìjọba fún ìdàgbàsókè ètò ọrọ̀ ajé lápapọ̀ orílẹ̀-èdè náà. Ààrẹ Tinubu sọ ọrọ̀ yìí níbí ọsẹ ayẹyẹ àwọn Òṣìṣẹ́…

Ìpínlẹ̀ Gombe Ṣetán Látí Ṣé Àtìlẹ́yìn Ìdókó-òwò Àwọn Ilé-iṣẹ́ Iná

Gómìnà Muhammadu Inuwa Yahaya, tí tún ṣé ìdánilójú ìjọba rẹ̀ láti ṣé àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ilé-iṣẹ́ aládàání lórí iná mọnamọna ní Ìpínlẹ̀ Gombe, èyí tí yóò ṣé ìdàgbàsókè àwọn ilé-iṣẹ́, ètò ọrọ̀ ajé àti arisiki àwọn ènìyàn. Gómìnà náà n…

Ààrẹ Tinubu Yóò Bá Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Sọ̀rọ̀ Lórí Ẹrọ Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ Orílẹ̀-èdè Yìí

Ààrẹ Bola Tinubu yóò ṣé àwọn ìkéde kàn sí àwọn orílẹ̀-èdè yìí ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kọkanlelọgbọn 31, Oṣù Keje ọdún 2023 ní àgó mẹ́fà ìrọlẹ́ (18:00 GMT). Agbẹnusọ fún Ààrẹ, Dele Alake, ló fí èyí hàn nínú àtẹ̀jiṣẹ́ kàn tó fí síta ní òwúrọ̀…

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú tí ṣetán látí yán ìgbìmọ̀ kàn látí ṣé ìwádìí “ọkọ àjàgbé èpò ní Ore ní ìjọba ìbílẹ̀ Odigbo ní Ìpínlẹ̀ Ondo tó gbá ẹ̀mí ọgbọ̀n. Ilé náà fẹ́ mọ́ ìdí ìṣẹ̀lẹ̀ náà pẹ̀lú wíwá Ojútùú sí láti má jẹ́ kí irú rẹ̀ wáyé mọ́ ní…
button