Ìfipágbàjọba: Àkókò Tí Ń Súnmọ́ Bí Àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà Ṣé Ń Gbáradì
Ọjọ́ méje tí àwọn Olùdarí Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà fún àwọn ológun ní Orílẹ̀-èdè Niger tí ń súnmọ́. Àkókò ọjọ́ méje náà ní láti dá Ààrẹ Mohamed Bazoum tí wọ́n dìtẹ gbàjọba lọ́wọ́ rẹ̀ sílẹ̀ pàdà, bí àpá méjèèjì ṣé níṣẹ́ ṣé.
Ní irọlẹ ọjọ́ Àìkú…