Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ṣé Àkíyèsí Àtúnṣe Òfin Ẹyà’wò Àwọn Ọmọ Ilé-ìwé

Ilé-ìgbìmọ̀ Àwọn Aṣojú tí ṣetán látí ṣé àtúnṣe òfin ẹ̀yá'wó ìrọ̀rún fún àwọn ọmọ ilé-ìwé gíga. Èyí wáyé lẹyìn tí Ààrẹ Bola Tinubu buwọ́lù òfin ẹ̀yá'wó àwọn ọmọ ilé-ìwé gíga. Alága tí Ìgbìmọ̀ abẹ́lé lórí ètò ẹ́yá'wó Àwọn ọmọ ilé-ìwé…

Á Ní Ìgbàgbọ́ Látí Yanjú Rògbòdìyàn Òṣèlú Ní Orílẹ̀-èdè Niger -ECOWAS

Àwùjọ ètò ọrọ̀ ajé ti Ìpínlẹ̀ Ìwọ̀-Oòrùn Áfíríkà, ECOWAS, sọ pé ó ní ìdánilójú pé ìpàdé ẹ̀lẹ́ẹ̀kejì rẹ̀ lórí ipò òṣèlú ní Orílẹ̀-èdè Niger yóò wá ojútùú ọlọjọ́ pípẹ́ sí aawọ̀ ìṣèlú ní Niger. Alága ECOWAS àtí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River Gbé Àwọn Ọkọ Àyọ́kẹ́lẹ́ Túntún Fún Àwọn Adájọ́

Gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River, Alàgbà Bassey Otu tí fí ọkọ túntún Ford Edge tọrẹ́ fún àwọn adájọ́ àgbà, lẹyìn oṣù kàn tí wọ́n ṣé àbẹwò sí ọfisi rẹ̀. Nígbàtí o n ṣé àfihàn àwọn ọkọ náà ní Calabar, Olú-ìlú tí Ìpínlẹ̀ Cross River, Gómìnà Otu…

Àyá Gómìnà Cross River Ṣé Ìlérí Àtìlẹ́yìn Fún Ìdáàbòbò Àyíká Ọmọdé

Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River, Ìyááfín Eyoanwan Otu tí ṣé ìlérí àtìlẹ́yìn fún ìmúṣẹ Òfin Ìdáàbòbò ẹ̀tọ́ àwọn ọmọdé ní ọdún 2023 ní ìjọba ìbílẹ̀ méjìdínlógún. Ó ṣé ìdánilójú náà làkókò ibaraẹnisọrọ pẹ̀lú Alàkóso Ètò Ìdáàbòbò ẹ̀tọ́…

Alága ECOWAS Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n Ẹsìn Islam, Ó Sí Fọwọ́sí Ìpàdé Wọ́n Pẹ̀lú Niger

Ẹgbẹ́ kàn tí àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n ẹsìn Islam tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ọjọ́rú ṣé ìpàdé pẹ̀lú Alága Ẹgbẹ́ àwon Orílè-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà (ECOWAS) àtí Ààrẹ Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu ní Ilé-iṣẹ́ Ìjọba àpapọ̀ ní Abùjá àti wọ́n sì gbà ìfọwọ́sí…

Àwọn Ọmọ Ogún Nàìjíríà Ṣé Ìlérí Ajọṣépọ̀ Fún Ìfẹ Orílẹ̀-èdè

Ẹgbẹ́ ọmọ ogún Nàìjíríà 'Nigeria Army NA' tí tún fí ìdí ìlérí àjọṣepọ̀ àtí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ̀ múlẹ̀ pẹ̀lú ọmọ ogún ojú omí fún ìfẹ orílẹ̀-èdè náà. NA ṣọ èyí dì mímọ̀ lórí ẹ̀rọ́ Twitter rẹ̀ ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ọjọ́ kàrún, Oṣù Kẹjọ, Ọdún…
button