Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Ní India

Ààrẹ, Bola Tinubu tí ṣé ìpàdé pẹ̀lú àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní India bó ṣé tẹnumọ́ ìwúlò àwọn onírúurú ẹyà tí orílẹ̀-èdè náà látí mú ìdàgbàsókè bá ètò-ọ̀rọ̀ àjé, ìmọ túntún àtí ìlọsíwájú àwùjọ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Aṣáájú…

Ọgọọgọrún Àwọn Ilé-ìwé UK Mìíràn Ní Á Tún Lè Dáwo, Mínísítà sọ

Àwọn ọgọọgọrún àwọn ilé-ìwé síi ní Orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ó lè wó lulẹ̀, Àkọwé Ẹ̀kọ́ tí Orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì Gillian Keegan tí sọ ní ọjọ́ Ajé lẹ́yìn tí àwọn aláṣẹ pàṣẹ kí wọ́n tí àwọn ilé-ìwé ọgọrùn lé mẹ́rin látí kojú èwù àti àjálù.…

Ààrẹ Àna Tí Nàìjíríà Fèsì Ọrọ̀ Ajẹ́bánú Àtí Ìbàjẹ́ Tí Mínísítà Àna Kàn Fí Ẹsùn Rẹ̀ Kán

Ààrẹ àna Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari sọ pé Mínísítà fún ètò ìdájọ́ tẹ́lẹ̀, Mohammed Adokie kó ní ẹnu látí sọ̀rọ̀ nípa ìdàgbàsókè ìwà ìbàjẹ́ lábẹ́ rẹ̀. Ní ìdáhùn sí àwọn ẹsùn tí Adokie fí kàn Ààrẹ náà láìpẹ́, Agbẹnusọ fún…

Ààrẹ Tinubu Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Olórí Àwọn Òṣìṣẹ́ Ológun Ṣáájú Àpéjọ G-20

Ààrẹ Bola Tinubu tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣé pàdé pẹ̀lú àwọn Olórí Ọmọ-ogun látí gbọ́ àwọn ipò ètò Ààbò látí ọdọ wọ́n lẹyìn iṣẹ́ wọ́n ṣáájú ìrìn-àjò lọ́ sí India látí kópa nínú ìpàdé G-20. Ìpàdé náà, èyí tó má ń wáyé lóòrèkóòrè ní…
button