Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ológun Àtí Àwọn Àsọ́bodè Nàìjíríà Ṣetán Látí Dáàbòbo Àwọn Ààlà Nàìjíríà

Ẹgbẹ́ ọmọ ogún Nàìjíríà tí sé àfihàn ìgbáradì rẹ̀ látí ṣé àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ àṣọ́bodè tí Nàìjíríà (Nigerian Custom Service NSC) látí bójútó ààbò ààlà àtí ìlànà àjọṣépọ̀ láìní ìrújú. Ọgá àgbà àwọn ọmọ ogún (COAS) Lieutenant General…

Ààrẹ Tinubu Bá Àwọn Ẹbí Olóyè Akintola Williams Kẹ́dùn

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Tinubu tí dárapọ̀ mọ́ ẹbí, ọrẹ àtí àwọn ojúlùmọ̀ Olóyè Akintọla Williams látí kẹ́dùn ikú rẹ̀. Ààrẹ ṣàpèjúwe Olóyè Williams Gẹ́gẹ́ bí ẹní tó ní ìmọ̀ nínú isẹ́ ìṣirò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àtí ní ìhà Áfríkà…

Ààrẹ Venezuela Yóò Ṣàbẹwò Sí Ìlú China Látí Ṣé Àtúnṣe Àtí Mú Àwọn Ìbátan Wọ́n Lágbára Sí

Ìlú Beijing sọ pé Ààrẹ Venezuela Nicolas Maduro yóò ṣàbẹwò sí Orílẹ̀-èdè China látí Ọjọ́ Ẹtì, látí mú ìbáṣepọ̀ Orílẹ̀-èdè méjèèjì lágbára sí. Ìdókó-òwò lórí èpò rọbi àtí ọnà látí sàn gbèsè pàdà ní àkòrí àbẹwò náà látí ọjọ́ kẹjọ sí…

Mali: Àwọn Aráàlú Mọ́kàndìnlàádọ́ta Pàdánù Ẹ̀mí Wọ́n Nínú Ikọlù Orí Omí

Àwọn onijagidijagan kọlù ọkọ ojú omí kàn ní àríwá Ìlà-oòrùn Mali, wọ́n sí pá o kéré jù àwọn aráàlú Mọ́kàndìnlàádọ́ta , àdele ìjọba sọ. Wọ́n tún sọ pé wọ́n kọlù ibùdó àwọn ọmọ ogún, tí wọ́n pá àwọn mẹ̀ẹ́dogún , làkókò tí àwọn ológun náà…

Ààrẹ Tinubu Yóò Dáàbòbo Àwa Obínrin Nàìjíríà Àtí Ró Wá Lágbára – Mínísítà

Mínísítà fún ètò àwọn Obìnrin lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Uju Kennedy-Ohanenye tí fí dá àwọn obìnrin lójú pé ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu tí ṣetán látí dáàbòbo àwọn Obìnrin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àtí ró wọ́n lágbára. Ohanenye sọ èyí lásìkò àbẹwò rẹ̀…

Àwọn Ọkọ Òfurufú Yóò Bẹ̀rẹ̀ Síi Ló Ojú-ná Pápá-kọ̀ Òfurufú Èkó Túntún

Lẹyìn ìṣẹlẹ iná tó ṣẹlẹ̀ láìpẹ́ yíì ní pápá-kọ̀ Òfurufú Murtala Muhammed tó wà ní ìlú Èkó, Nàìjíríà, Àjọ Élétó Ọkọ Òfurufú nílẹ̀ Nàìjíríà (FAAN) tí dárí ṣíṣètò àwọn àrinrìn àjò gbà Ojú-ná túntún ní kíákíá. Mínísítà tí Òfurufú àtí…
button