Ẹgbẹ́ Àjaja-Gbára Lebanon Gbé Omí-Ìjà Káná Pẹ̀lú Israel
Ẹgbẹ́ ọmọ ogún Hezbollah tí Lebanoni tí tá ọ̀pọ̀lọpọ̀ rọkẹẹti sí ipò àwọn ọmọ ogún Israel ní àgbègbè kàn tí wọ́n ń já sí ní ààlà Orílẹ̀-èdè Syria àti Israel ní Golan Heights.
Hezbollah sọ nínú àlàyé kàn pé ikọlù náà ní àwon ṣé láti fí…