Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Lórí Ìwé Àbádòfin NABRO

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí tún gbé ìwé àbádòfin fún ìdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ètò ìṣúná àtí ìwádìí tí ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, NABRO èyítí Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin tẹlẹ́ tí ọdún 2007 kò lè fí óntẹ̀ lù, ní wọ́n tún tí gbé jáde báyìí.…

Ààrẹ Tinubu Ṣé Àjọyọ̀ Pẹ̀lú Alàgbà Adeboye Bó Ṣé Pé Ọmọ Ọdún Méjìlélọ́gọ́rin

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kí Alábòójútó Gbogbo Ìjọ Redeemed Christian Church of God (RCCG), Pàsítọ̀ Enoch Adeboye, ní bó ṣé pé ẹní ọdún méjìlélọ́gọ́rin ní ọjọ́ kejì, oṣù kẹ́ta. Ààrẹ darapọ̀ mọ́ àwọn ọmọ lẹ́yìn Krístì ní ìdúpẹ́ fún…

Ààrẹ Tinubu Kí Olufunke Gbajabiamila Kú Oríire Ọjọ́ìbí mẹ́rìnlèlàádọ́rùn-ùn

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí kí Obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ alága ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n dìbo yàn ní ìpínlẹ̀ Èkó, Lateefat Olufunke Gbajabiamila kú oríire ọjọ́ìbí bó ṣé pé ọmọ ọdún mẹ́rìnlèlàádọ́rùn-ùn. Nínú ọrọ̀ kàn tí Agbẹnusọ fún Ààrẹ, Ajuri…

Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá Nàìjíríà Bẹ̀rẹ̀ Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Rẹ̀ Lójúnà Látí Dáàbòbo Àwọn Ilé-ìwé

Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣé àfihàn àwọn òun èlò ààbò tó dára jùlọ àtí bíi ètò ìkẹ́kọ́ fún Àwọn alàkóso tí Ìpínlẹ̀ kọọkàn fún Ilé-ìwé àwọn ọlọ́pàá 'School Protection Squad (SPS)' jakejado Orílẹ̀-èdè yìí. Èyí wà láti…

Ọwọ́ Bá Àwọn Ọ̀bàyéjẹ́ Mẹ́ta Kàn Àtí Àwọn Ọdaràn Méjì Mìíràn

Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá tí Olú-ìlú Nàìjíríà (FCT) tí mú àwọn ọdaràn mẹ́ta (3) kàn tí wọ́n ń jí ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ gbé ní Abuja. Kọmiṣana ọlọ́pàá tí FCT, C.P Benneth Igweh, sọ pé àwọn afurasi náà jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Ọkùnrin mẹ́rin (4) tó ń jí tàbí já…

Ilé-iṣẹ́ Ọmọ-ogún Kọ́ Ìròyìn Jìbitì Tó Lọ́ Káàkiri Lórí Ayélujára

Ilé-iṣẹ́ ọmọ-ogún Nàìjíríà tí bú ẹnú àtẹ lú àwọn ìròyìn lórí jìbitì owó tó ń lọ́ káàkiri lórí ẹ̀rọ ayélujára àwùjọ, tí wọ́n sọ pé ó wá látí ọdọ ọmọ-ogún. Ẹgbẹ́ ọmọ-ogún nínú ọrọ̀ kàn tí Olùdarí Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ pẹ̀lú aráàlú, Major…

Olórí Ààbò Gbá Àwọn Ọdọ Níyànjú Látí Ṣé Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Ẹ̀ṣọ Ààbò

Wọ́n tí gbá àwọn ọdọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nímọ̀ràn látí ṣé ìrànlọ́wọ́ àtí àtìlẹ́yìn olóbó fún àwọn ẹ̀ṣọ aláàbò látí dènà àwọn ìpèníjà ààbò tí ń ṣẹ̀lẹ̀ Lórílẹ̀-èdè yìí. Olórí Àwọn Òṣìṣẹ́ Ààbò Nàìjíríà, CDS, General Christopher Musa sọ́…

Ọdọmọkùnrin Nàìjíríà Kàn Rìn Ìrìn Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin Kìlomíta Láti Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Olórí Ààbò

Awakọ̀ ọmọ odún mọkàndínlọ́gbọ̀n (29) ọmọ Ìpínlẹ̀ Gombe, Mallam Suleiman Rabiu tí rìn Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin kilomita (700km) láti Ìpínlẹ̀ Gombe wá sí Abuja láti mọ́ rírí iṣẹ́ Olórí Ààbò Nàìjíríà, Gen. Christopher Gwabin Musa. Mallam Suleiman,…
button