Take a fresh look at your lifestyle.

Agbọrọsọ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Kwara Tí Rọ́ Ìjọba Ìpínlẹ̀ Náà Látí Ṣẹ̀dá Ilè Ìkọṣẹ́ Fún Àwọn Ọdọ

Agbọrọsọ, Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Kwara, Yakubu Danladi-Salihu tí gbá Ìjọba Ìpínlẹ̀ náà ní ìmọràn látí dá àwọn ilé ìkọ́ṣẹ́ ọwọ́ sílẹ̀ síi fún àwọn ọdọ láti jẹ́ kí wọ́n lè ní ìgbẹ́kẹlé nínú àrà wọ́n. Danladi-Salihu sọ̀rọ̀ yìí làkókò…

Mínísítà Pé Fún Àtúnṣe Ìwé-ẹ̀kọ́ Tí Ilé-ìwé Àwọn Ọlọ́pàá

Ilé-iṣẹ́ tí àwọn ọlọ́pàá sọ pé ó ṣé dàndàn fún àtúnyẹwò àti ìmúdójúìwọ̀n tí Ìwé-ẹ̀kọ́ tí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ọlọ́pàá Nàìjíríà látí ríi dájú pé ó wà ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ wọ́n Lágbayé. Mínísítà fún ọrọ àwọn ọlọ́pàá Alàgbà Ibrahim Gaidam…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣé àbẹwò sí àwọn tí morí bọ́ nínú ìsẹ̀lẹ̀ iná mọ̀nàmọ́ná tó waye ní ọjọ́ Àbámẹ́ta tó kọjá ní Ìpínlẹ̀ Cross River ní Olú-ìlú náà, Calabar. Ìjọba, nípasẹ àjọ tó n dárí iná mọ̀nàmọ́ná lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí…

Ìgbákejì Ààrẹ Shettima Rọ́ Ìgbìmọ̀ Àmúṣẹ́yá Túntún Tí Àwọn Arìnrìn-àjò Sí Ilẹ̀-mímọ́ Látí…

Ìgbákejì Ààrẹ Kashim Shettima tí rọ́ àwọn ìgbìmọ̀ àmúṣẹ́yá túntún tí Ìgbìmọ̀ Arìnrìn-àjò àwọn Onígbàgbọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà (Nigerian Christian Pilgrim Commission NCPC) látí ṣ'iṣẹ́ náà dójú àmì. Nígbà tó n bá àwọn aṣojú NCPC náà…
button