Orílẹ̀-èdè Gambia Ṣètò Ìgbógun Tí Ikú Ọwọọwọ Àwọn Ọmọdé
Gambia ṣé ìgbésẹ Ìlera ọtún pẹ̀lú ìṣàkóso tó dára jùlọ lórí
bí wọ́n ṣé ń kò òògùn wọlé lẹyìn ikú àràmàndá dosinni tí àwọn ọmọdé.
Aare Gambia Adama Barrow sọrọ lórí ìṣẹlẹ̀ náà pé:
"Àwọn ará ìlú Gambia, àwọn olùgbé ìlú Gambia, mo ṣé…