Bùhárí Ṣọ̀fọ̀ Ààrẹ Bishop Desmond Tutu
Ààrẹ Muhammadu Buhari ti kí Ààrẹ Cyril Ramaphosa, àwọn ọmọ orílè-èdè South Africa àti ẹgbẹ́ ọmọ ìjọ Kírísítẹ́nì kárí ayé, pàápàá jù lọ àkójọpọ̀ ìjọ Áńgílíkà, ní orúkọ ìjọba àti àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,lori ikú ẹni…