Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbúgbàmù Tó Wáyé Ní Ilú Ìbàdàn: Makinde Gbé Àkọsílẹ ìṣẹ̀lẹ̀ Náà Ká Iwájú Ààrẹ Tinubu

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,Seyi Makinde ti gbe àkọsílẹ ìṣẹlẹ ìbúgbàmù to waye ní ọjọ Kẹrindinlogun oṣù yìí ni agbègbè Adeyi, ni Bódìjà, ni ìlú Ìbàdàn ka iwájú Ààrẹ Bola Tinubu. Makinde ló gbé ìgbésẹ yìí ni òpin ọsẹ tó kọjá, nígbà tó tún fi…

Ìpèsè Omi Tó Mọ́ Gaara: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Pe Fún Ìrànlọ́wọ́ Àjọ ‘Water Aid…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti pe fún ìrànlọ́wọ́ pàtàkì lati ọ̀dọ̀ ilé iṣẹ́ kan tí kìí ṣe ti ìjọba, 'Water Aid International' láti se àgbédìde ẹ̀ka tó n mójú tó ìpèsè omi tó mọ́ gaara. Gẹ́gẹ́ bi atejade ti Kọmísánnà fún Ìròyìn, Dọtun Oyelade fi…

A Ṣẹ̀ Ṣẹ̀ Ń Mẹ́yẹ Bọ̀ Lápò Ni: Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles Ti Fi Àgbà Han Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Ivory…

Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Ivory Coast  àti Ikọ̀ Agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles figagbaga bi bọọlu ṣe bẹrẹ lori paapa ni ilaji akọkọ, ko si ẹni to mi àwọ̀n ninu orílẹ̀-èdè mejeeji yii Ṣugbon Nigba ti wọn bẹrẹ ilaji keji, Super Eagles ni anfaani lati mi…

Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìbúgbàmù Nílùú Ìbàdàn: Olúbàdàn Kẹ́dùn Pẹ̀lú Àwọn Tó Lùgbàdì Ìjàmbá

Olúbàdàn Ilẹ̀ Ìbàdàn Ìbàdàn, Ọba Lekan Balogun, Allí Okunmade II ti ṣe àbẹ̀wò sí àgbègbè tí ìbúgbàmù àwọn ohun èlò ìwakùsà ti ṣe ìjàmbá fún ọpọlọpọ èèyàn, nígbà tí àìmọye náà pàdánù ẹ̀mí wọn, tó sì gbàdúrà kí Ọlọrun tẹ gbogbo wọn sáfẹ́fẹ́…

Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìbúgbàmù Ni Ìlú Ìbàdàn: Ènìyàn Mẹ́tàdínlọ́gọ́rin (77) Fara pa.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ labẹ àkóso Gómìnà Seyi Makinde ti ṣàlàyé ìṣẹ̀lẹ̀ pe ìbúgbàmù tó wáyé ní agbègbè Awolowo ni ìlú Ìbàdàn lo nìí ṣe pẹ̀lú àwọn ẹ̀tù (Explosives) eléyìí tí àwọn tó n wa Kùsà lọ́nà àìtọ́ ko pamọ́ sínú ilé kan ni agbègbè náà.…

Makinde Sí Àwọn Èèyàn Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́: Ẹ Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ké sí àwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ náà láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò ki wọn sì fi to won létí tí wọn ba ri ohunkóhun tó lòdì. Makinde ló sọ èyí níbi ayẹyẹ tó sami ìrántí àwọn ológun tó ṣubú lójú…

Ìpèsè Iná Mọ̀nà-mọ́ná: Ẹ Fa Gbogbo Bàsèjẹ́ Ohun Èlò Àmúṣagbára Le Agbófinró Lọwọ – Adelabu

Mínísítà fún ohun Àmúṣagbára ni Orílé èdè Nàìjíríà, Adebayo Adelabu ti gba gbogbo ọmọ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà níyànjú láti fi to àwọn agbófinró létí ti wọ́n bá kófìrí ẹnikẹni ni agbègbè tí àwọn ohun èlò Àmúṣagbára wà. Adelabu tẹnu mọ́ pé eyi…
button