Makinde Pé Fún Àlàáfíà Laarin Awọn Olùfẹ̀hónú Hàn, Ó Ṣèlérí Láti Pe Akiyesi Ijoba Àpapọ̀.
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti pe fún àlàáfíà láàárín àwọn ènìyàn tó n fi ẹ̀hónú hàn látàrí ebi àti ìyàn tí n ba àwọn ọmọ Orilẹ èdè Nàìjíríà fínra, nígbà tó sì ṣèlérí láti gbé ìbéèrè wọn lo sí iwájú Ààrẹ Bọla Tinubu, tó sì gba wọn…