Take a fresh look at your lifestyle.

Ta Ni Yóò Rẹ́rìn-ín Ayọ̀ Láàrin BAT, ATIKU Àti OBI Lẹ́yìn Tí Ilé-ẹjọ́ Bá Gbé Ìdájọ́ Kalẹ̀ Lórí Ìbò…

Lónìí, ọjọ́ kẹfa, oṣu kẹsan-an, ọdún 2023 ni ile ẹjọ kọtẹmilọrun to n gbẹjọ awuyewuye to suyọ ninu ibo ààrẹ orilẹ-ede Nàíjíríà èyí ti Bola Tinubu ti jawe olubori yoo da ẹjọ ti ẹgbẹ oṣelu LP, PDP, APM, APP ati AA pe ajọ eleto idibo INEC pe…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Da Àwọn Ṣọ́ọ̀bù Ìtajà Tó Wà Lára Ògiri Ilé Ẹ̀kọ́ Wo Lulẹ̀

Lára akitiyan Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti mú ayípadà dé bá àmójútó àti ìmọ́tótó àyíká àwọn ilé ẹ̀kọ́, Gómìnà Seyi Makinde ti fún gbogbo ẹni yìówù tó bá ní ṣọ́ọ̀bù ni àyíká ògiri àwọn ilé ẹ̀kọ́ tó jẹ́ ti ìjọba ni gbèdéke ọ̀sẹ̀ kan láti fi…

Àwọn ilé ìfowópamọ́,òsìsẹ́ ìjọba, ilé ìwòsan ,kọ etí ikún sí ìyansẹlódì ẹgbẹ́ òsìsẹ́ NLC nílùú Abùjá

Bí ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà (NLC) Se bẹ̀rẹ̀ ìwọ́de ọlọ́jọ́ méjì wọn láti fi se ìkìlọ̀ fún ìjọba àpapọ̀. Síbẹ̀, púpọ̀ nínú àwọn ilé ìfowópamọ́ tó wà nílùú Abùjá ló ń bá isẹ́ wọn lọ pẹrẹu láìsí ìdíwọ́.lára àwọn ilé ìfowópamọ́…

Ìjọba Àpapọ̀ Gba Àwọn Ọdọ Níyànjú Láti Kọ Ẹkọ Lára Olóògbé Taiwo Akinkunmi

Ìjọba Àpapọ̀ ti ké sí àwọn ọdọ ilẹ̀ yìí látì kọ ẹkọ lára Olóògbé Taiwo Akinkunmi, ẹni tó ya àwòrán Àsìá Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lásìkò tó jẹ́ ọdọ Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ẹni tíì ṣe Mínísítà fún Ìròyìn àti Ìlanilọ́yẹ lorilẹ èdè Nàìjíríà,…

Panpẹ Àjọ EFCC Mú Ogún Afurasí Oníjìbìtì Orí Ẹ̀rọ Ayélujára Ni Ìlú Ìbàdàn

Panpẹ àwọn òṣìṣẹ́ Àjọ to n gbógun ti ṣíṣe owó ìlú kúmọkùmọ, EFCC Ẹkùn tí Ìbàdàn ti mú ogún afurasí oníjìbìtì orí ẹ̀rọ ayélujára. Gẹ́gẹ́ bíi àtẹ̀jáde tí Olórí Ẹ̀ka ìròyìn àti ìpolongo fún àjọ náà, Wilson Uwujaren fi síta ṣe ṣàlàyé pé,…
button