Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdáhùn Sì Ìbéèrè Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́: Makinde Yan Ìgbìmọ̀ Ẹlẹ́ni Mọ́kànlá Láti Wá Ọ̀nà Àbáyọ

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti yan ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni mọ́kànlá kan láti wá ojútùú sí ìbéèrè àwọn ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Nígbà tó n fi ìgbìmọ̀ náà, eléyìí tí Akọwe Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọjọgbọn Olanike Adeyemo jẹ́…

Ayẹyẹ Ọdún Kẹtàlélọ́gọ́ta Òmìnira: Makinde Pé Fún Àfojúsùn Orílẹ̀ Èdè Ọ̀tun

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti gba ọmọ Orilẹ èdè Nàìjíríà níyànjú láti ni ìran àti ṣíṣe fún Orilẹ èdè ọtun gẹ́gẹ́ bíi won ṣe n ṣe ayẹyẹ ọdún Kẹtàlélọ́gọ́ta ti Orilẹ èdè Nàìjíríà gba òmìnira Gómìnà, ẹni tó fi àsìkò ayẹyẹ ọdún…

Ọ̀RỌ̀ ÀÀRẸ TINUBU LÓNÌÍ ỌJỌ́ AYẸYẸ ÀYÁJỌ́ ỌDÚN ÒMÌNIRA LÓRÍLẸ̀DÈ NÀÍJÍRÍÀ

Ẹ̀yin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà, Pẹ̀lú ìdùnnú ọkàn ní mo fi n ba yin sọrọ lónìí ọjọ́ kinni, oṣu kẹwàá, Ọdun 2023, Ọjọ́ ayẹyẹ ọdún òmìnira ti Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà pé Ọdún Mẹ́tàlélọ́gọ́ta gẹ́gẹ́ bíi  Ààrẹ…

Eid-el Maulud: Makinde Pé Musulumi Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fún Àdúrà Àti Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Wọn

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti pe gbogbo Mùsùlùmí láti tẹ síwájú nínú adura àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ fún àwọn adarí Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Makinde, nínú àtẹ̀jáde tí Akọwe ìròyìn rẹ̀, Suleiman Olarewaju fi síta ló sọ…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kìlọ̀ Fún Àwọn Tó N Kólé Sórí Ilẹ̀ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti kìlọ̀ fún àwọn tó n kólé sórí ilẹ ilé ẹkọ tó jẹ́ ti Ìjọba láti jáwọ nínú irú iwa bẹẹ Ẹni tíì ṣe Kọmísánnà fún Ètò Ẹ̀kọ́, Sáyẹnsì àti Ìmọ̀ Ẹ̀rọ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Abdulwaheed Adelabu lo ṣe ìkìlọ̀ yìí lásìkò tó n ṣe àbẹwò…

Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn VON Ké Gbàjarè Síta Bí Wọ́n Ṣe Pàdánù Ọ̀kan Lára Àwọn Akọ̀ròyìn Wọn, Hamisu…

Pẹ̀lú Ibanujẹ Ọkàn ni Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn VON gba iroyin Ibanujẹ ikú Hamisu Danjigba, Akoroyin fún Ilé Akede Nàíjíríà (VON) ní Ìpínlẹ̀ Zamfara, iṣẹlẹ ibanujẹ yii to ṣele láti ọwọ́ àwọn ajínigbé. Ikú rẹẹ̀ jẹ nkan Ibanujẹ tó tún ran wa létí…

Olóògbé Taiwo Akinkunmi Ti Ṣe Gudugudu Méje,Yàyà Mẹ́fà Láti Mú Ìsọ̀kan Bá Nàìjíríà – Garba…

Ọ̀kan lára Olùdarí ẹgbẹ́ Project One Oluwarotimi Akinnadeju, ti ní ìtàn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kò pé tí a kò bá sọ nípa ẹni tó ya àwòrán àsìá ìyẹn National flag orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tẹ̀síwájú pé Ásíà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sàlàyé nípa…
button