Take a fresh look at your lifestyle.

Makinde Kẹ́dùn Ikú Adarí Obìnrin Fún Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Stella Effah-Attoe

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde tí fi àìdùn inú rẹ̀ hàn sí ikú Adarí Obìnrin fún Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP, Ọ̀jọ̀gbọ́n Stella Effa-Attoe. Àtẹ̀jade ti Akọwe ìròyìn fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Suleimon Olanrewaju lo ṣàlàyé pé, Makinde fí ìròyìn ikú…

Ẹgbẹ́ Ajàfẹ́tọmọnìyàn Ṣèlérí Atilẹyin Fún Àjọ EFCC, Ẹkùn tí Ìbàdàn

Àwọn Ẹgbẹ́ Ajàfẹ́tọmọnìyàn ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti ṣèlérí atilẹyin fún Àjọ EFCC nínú ìgbìyànjú rẹ láti gbógun ti ìwà ṣíṣe owó ìlú kúmọkùmọ àti awọn ìwà ìbàjẹ́ míràn. Àtẹ̀jáde tí Adarí ẹ̀ka ìròyìn àti ìkéde fún Ajo EFCC, Ẹkùn tí Ìbàdàn, Dele…

Makinde Pé Fùn Ifọwọ́sowọ́pọ̀ Èèyàn Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fún Àyíká Fún Ayika To Rẹwà

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde tí ké sí gbogbo èèyàn Ìpínlẹ̀ náà láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Ìjọba láti mú kí àyíká àti agbègbè jákèjádò Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ le rẹwà ni ìbámu pẹ̀lú àlàkalẹ̀ "Gbé ìgbésẹ Ara Rẹ" (Own Your Action) ti Ilé iṣẹ tó n rí…

Ìdènà Ẹ̀kún Omi: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fẹ Ojú Odò Nlánlá Àti Odò Keekeke Mẹ́jọ

Ni ìgbáradì láti dènà ẹ̀kún omi, Ìjọba Ìpínlè Ọ̀yọ́ ti fẹ ojú àwọn odò nlánlá àti kekeeke mẹjọ jákèjádò àwọn ẹkùn ní Ìpínlè Ọ̀yọ́. Kọmísánnà fún Ọ̀rọ̀ Àyíká àti Ohun Alumọni, Ayàwòrán ilé Abdulmojeed Mogbonjubola, ẹni tí Olùdarí ilé iṣé…

Ẹ̀sùn Jìbìtì Ọgọfa Mílíọ̀nù Àti Aabọ Náírà: Ilé Ẹjọ́ Sún Ìgbẹ́jọ́ Sí Ọjọ́ Kẹrin Oṣù Kọkànlá

Ilé Ẹjọ́ Gíga to wa ni ìlú Ìbàdàn tíì ṣe olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni Ẹkùn Gúsù Ìwọ̀ Oòrùn Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà, ti pinnu láti bẹrẹ igbẹjọ lórí ẹ̀sùn jibiti tí o fi kan Obakin Emmanuel Ajibola, ni ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún yìí, gẹ́gẹ́ bí…

Makinde Pe Fun Ìrànlọ́wọ́ Láti Gbé Ètò Ẹkọ Gòkè Àgbà Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Gómìnà Ìpínlẹ̀ àwọn ọmọ jẹ lógún, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jáde láti gbárùkù ti Ìjọba ni ọ̀nà àti mú ayípadà dé bá ètò ẹ̀kọ́. Makinde lo sọ ọ̀rọ̀ yìí ní ile ẹ̀kọ́ Government College Ìbàdàn (GCI) tó wà ní agbègbè Àpáta ni Ilú Ìbàdàn tíì ṣe olú ìlú…

Ṣíṣe Ìgbọ̀nsẹ̀ Ní Ìta Gbangba: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Pinnu Ìjìyà Fún Arúfin

Lára akitiyan láti fi òpin sí ṣíṣe ìgbọ̀nsẹ̀ sí ìta gbangba, Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti pinnu ìjìyà fún ẹni yìówù tó bá ṣe igbọnsẹ tàbí tó bá da idọti sí ìta gbangba ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Komisana fún Ìròyìn àti Ìlanilọ́yẹ, Dọtun Oyelade ló sọ…

Owó Oṣù Òṣìṣẹ́ Fẹ̀yìntì: Ìjọba Fi Ọwọ Sí Sisan Igba Mílíọ̀nù Àti Mẹ́fà Náírà (N206m) Owó Òṣìṣẹ́…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fi ọwọ́ sí sisan igba Mílíọ̀nù àti Mẹ́fà Náírà (N206m) owó oṣù òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì, nígbà tó fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé Mejilelaadorun (92) òṣìṣẹ́ fẹ̀yìntì ni o rí owó gbà nínú owó tí ìjọba ti san sẹ́yìn. Kọmísánnà fún…
button