Take a fresh look at your lifestyle.

Ìṣúná-Owó 2024: Àpapọ̀ Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Èkó bẹ̀rẹ̀ àyẹ̀wò fínnífínní fún àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba.

Àpapọ̀ Ìgbìmọ̀ fún Ètò Ìṣúná owó Ogden 2024 nínú Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó bẹ̀rẹ̀ àyẹ̀wò fínnífínní lórí Ètò ìṣúná owó àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba, ẹ̀kà ilé-iṣẹ́ ìjọba àti àwọn Àjọ ilé-iṣẹ́ ìjọba ní Ìpínlẹ̀ Èkó, kí ètò ìṣúná owó wọn fún ọdún…

Ẹnú gbẹ: ìjọba àpapọ̀ kọ̀ láti san owó oṣù fún òṣìṣẹ́ rẹ̀ láti fi sọdún kérésìmesì.

Bí inú àwọn ènìyàn se ń dùn, tí wọ́n ń jó, tí wọ́n sì ń yọ̀ bí ọ̀dun kérésìmesì yìí se wọlé dé. Ṣe ni, àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àpapọ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà fojúro tí inú ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọ́n ṣì bàjẹ́ bí ìjọba àpapọ se fárígá láti máa san owó oṣù fún…

Ayẹyẹ Ọdún Kérésìmesì:Olúbàdàn Ké Sí Gbogbo Èèyàn Láti Kọ Ẹkọ Lára Pàtàkì Ìbí Jésù

Gẹ́gẹ́ bí ọmọ lẹ́yìn Kristi jákèjádò Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ṣe darapọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ wọn lágbayé fún ayẹyẹ Kérésìmesì ti ọdún yìí, Olúbàdàn Ilẹ̀ Ìbàdàn, Ọba Lekan Balogun, Allí Okunmade II ti gba gbogbo wọn níyànjú láti kọ ẹ̀kọ́ lára ibí…

Ọ̀mọ̀wé Akinwunmi Adéṣínà gba Àmì ẹ̀yẹ Àwòkọ́ṣe Iṣẹ́ Aṣíwájú Awólọ́wọ̀ ti ọdún 2023

Ìgbìmọ̀ Ìdíje Àmì ẹ̀yẹ Ìdábilọ́lá pàtàkì fún Àwòkọ́ṣe Iṣẹ́ Aṣíwájú Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ti kéde Ọ̀mọ̀wé Akínwùnmí Adéṣínà, Ààrẹ Ilé Ìfowópamọ́ fún Ìdàgbàsókè Ilẹ̀ Áfíríkà, tí ó jẹ́ Mínísítà tẹ́lẹ̀ fún Ọ̀rọ̀ Iṣẹ́ àgbẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,…

Ilé Ẹjọ́ Rán Oníjìbìtì Olókoòwò Kan Ṣẹ́wọn Ọdún Márùndínlọ́gọ́rin Ní Ìlú Ìbàdàn

Onídàájọ́ Bayo Taiwo ti ilé ẹjọ́ jọ́ gíga to jókòó ní ìlú Ìbàdàn tí rán Olaniyan Gbenga Amos lo sí ẹwọn ọdún Márùndínlọ́gọ́rin fún onírúurú ẹ̀sùn tó jọ mọ́ jibiti òkòwò. Olaniyan tíì ṣe olùdarí àti olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ òkòwò "Crime Alert…

Makinde Gbé Ọpa Àṣẹ Fún Oba Ghandi Gẹgẹ Bíi Ṣòún Ogbomoṣo Kọkànlélógún (21)

Ìlú Ogbomoso gba àlejò àwọn èèyàn jankan-jankan bíi Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ṣe gbé ọ̀pá àṣẹ fún Ọba Ghandi Afọlábí Olaoye, Orumogege III, gẹ́gẹ́ bíi Soun Ogbomoṣo ẹlẹ́ẹ̀kọkànlélógún (21). Ayẹyẹ ìgbé ọ̀pá àṣẹ fúnni náà ló wáyé…

Ilé Aṣòfin Èkó ti gba Àbádofin ètò Ìṣúná owó ìlú wọlé ní ìgbà kejì.

Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó ti gba Àbádofin ètò Ìṣúná owó ọdún 2024 tí Ìpínlẹ̀ Èkó òní Tírílíọ́nù Méjì lé Bílíọ́nu méjì lé díẹ̀ náìrà (N2. 224 T) ní ìgbà kejì. Nígbà tí wọ́n ń gbóríyìn fún Gómìnà Babájídé Sanwo-Olu fún…

Gómìnà Sanwo-Olu ṣàbẹ̀wò sí gbàgede ìpàdé àpérò àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Ilé Aṣòfin Èkó lórí ìṣúná owó 2024.

Gómìnà Sanwo-Olu ti Ìpínlẹ̀ Èkó ṣàbẹ̀wò sí gbàgede ìpàdé àpérò àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó lọ́jọ́ Àbámẹ́ta Satide, níbi tó ti ṣàpèjúwe àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Ilé Aṣòfin náà gẹ́gẹ́ bí èyí tó fakọyọ láàárín àwọn akẹgbẹ́ wọn.…
button