COVID-19: Nàìjíríà Nílò Ògùn Corona Si
Ní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀, ní ìlú Paris, orílẹ̀ - èdè Faranse ni Ààrẹ Buhari ti gba àwọn olórí, ààrẹ àti gbogbo ilé-iṣé tó ń mójútó ìlera ní mòràn láti pèsè ògùn corona lọ́pọ̀ fún àwọn ará ìlú.
O tesiwaju, o sọ…